CAC HB Yoruba Hymn 1 - WikiLyrics
Browse Lyrics A-Z
A | B | C | D | E | F | G | H | I | J | K | L | M | N | O | P | Q | R | S | T | U | V | W | X | Y | Z

CAC HB Yoruba Hymn 1

1 Ago re wonni ti ni e wa to. Oluwa awon omo ogun. OD.84:1 CM
1 """Olu s`agun tan e ni re
Fi ara re han wa
Bo ti fun wa nile adua
Mokan wa gbadura"""
2 "Fi ami ife re han wa
So ireti wa ji
Se ri bukun re sori wa
Ka wa le ma yin O"
3 "Ki fe ati alafia
Ko ma gbe ile yi Fi ro ra fokan iponju
M okan ailera le ."
4 """Fe ti igbo aya igbase
Oju riran fun wa
Tan imole re l`atoke Ka dagba l`o re ofe "
5 """Ka fi gbagba gb oro re
Ka fi gba gbo bebe
A ti niwaju Oluwa
Ka se aroye wa. Amin "
Related Lyrics

Disclaimer: All The mp3 Lyrics on Wikilyrics are submited by various people and they have right on the contents they submited, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download.