Baba, a tun pade l'oko Jesu Yoruba Hymn - WikiLyrics
Browse Lyrics A-Z
A | B | C | D | E | F | G | H | I | J | K | L | M | N | O | P | Q | R | S | T | U | V | W | X | Y | Z

Baba, a tun pade l'oko Jesu Yoruba Hymn

 Baba, a tun pade l'oko Jesu

A si wa teriba lab'ese Re

A tun fe gb‘ohun wa soke si O

Lati Wa anu, lati korin 'yin.


Ayin O fun itoju ‘gbagbogbo,

Ojojumo l‘ao ma rohin ‘sc re;

Wiwa laye wa, anu Re ha ko?

Apa Re ki 0 fi ngba ni mera?


O se! Ako ye fun ife nla Re,

A sako kuro lodo Re poju;

Sugbon kikankikan ni O si np

Nje a de, a pada wa ‘le, Baba.


Nipa oko t‘0 bor'ohun gbogbo

Nipa ife t'o ta 'fe gbogbo yo,

Nipa eje ti a ta fun ese,

Silekun anu si gbani si ‘le.

   

Amin.

Related Lyrics

Disclaimer: All The mp3 Lyrics on Wikilyrics are submited by various people and they have right on the contents they submited, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download.