Ijewo Igbagbo (The Apostles Creed) - Yoruba version
Mo gba Olorun Baba wa Eledumare gbo
Eleda Orun oun aiye
Mo gba Jesu Kristi gbo
Omo Re nikan soso Oluwa wa
Eniti a fi Emi mimo loyun
Eniti a bi ninu Maria Wundia
Eniti o jiya lowo Pontu Pilatu
Eniti a kan mo agbelebu
Eniti oku, ti a si sin
O sokale repo oku
Ni ojo keta, O jinde kuro ninu oku
O re oke Orun, O si joko lowo otun Baba wa Eledumare
Nibe, la o ti se idajo aiye awon oku
Mo gba Emi mimo gbo
Ijo Celestial mimo
Idapo awon eniyan mimo
Idariji ese
Ajinde ni isa oku ati iye ti ko nipekun. Amin.
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.