Apekeola - Ogbogo F’ole Mi Lyrics

 

Apekeola OGbogo F’ole Mi

Apekeola OGbogo F’ole Mi Mp3 Lyrics


Oje kaye ya mi ni were

Lilo bibo mi Oja si rere

isan ara mi odemi modupe

Emi ti mo ngba simu o

Mio fi ile iwosan se ibugbe tebitebi

Bi 2020 se leto

Ofi aanu bami lo tile tile taratara


Ogbo go folole mi

Ogbo go folole mi

Ehhh

emi alaileniyan rara

ode pada wa gbogo Fole mi


Eni nla olodumare toto

Eni nla olodumare iba re


Wiwolule bi ate ileke

Araba ribiti

aribirabata

Alejo to nsonile kanri kese

Emi inu awon wooli tooto

Ekerin ninu ina

Oloruko nla

oloruko egbaagbeje

Onikan sole aye ro

eh ehe

Ese Ojo gbogbo

Balogun ninu awon orun


Balogun ninu awon orun

Sebi iwo larugbo ojo

adagba matepa

adagba malo gilai

baba mi to nwo kenbe wo ibi Ija

Goolu iyebiye

Messaiah

Oba aditu

Kikida Ola

Oba toloyun ara re to gbebi ara re

Oba todawasi

To kawaye

Ki ise mimo se


Aaanu re nimori


Iran mi omo eni to pataki laye

Sugbon owa gbogo fole mi

Opolopo lojade ninu iru ile ti moti jade wa

atije oma nira


Gbogbo awa ti oni ireti

tawa da eni to npada funi nile

Seebi aanu lo fohun lori lekan

Big brother

Ogbogo fole mi nigba timio lero

ti mio leni kan kna

mi o mo Dangote

Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.

Post a Comment

0 Comments
* Please Don't Spam Here. All the Comments are Reviewed by Admin.

Ads Area

Disclaimer: All The Lyrics, Stories, Hymn, Poem & Anthem on Wikilyrics are submitted by various people and they have right on the contents they submitted, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download. If you feel one of your asset should not be here please request take down.