Iru Iriri Lyrics - Mr Gbera ft. Adeyinka Alaseyori Download

 

Mr Gbera - Iru Iriri ft. Adeyinka Alaseyori Download Mp3 Lyrics

Ohun gbogbo to jababara fun won

sebohun lofi sara fun wo

Ohun toje ipalara fun won

ara irelofi jasi femi

tori moranugba ni


Ohun to lakoja to fa eri

lofa iku opolopo

oje dupe


Ona to hun lo to nmu onje wale

lomu opo lo orun oje dupe

Ona ofun re oda ona iku

oje dupe

Omo tori gbedani ohun logba emi opolopo oje dupe


Iru iriri ti mori gba la won kori

Sugbon anu ti morigba woko ri gba


Iru iriri ti mori gba la won kori

Sugbon anu ti morigba woko ri gba


Orisirisi iriri lohun sele

Aimoye nkan ta ogbori losele

Gbogbo orile ede ohun be ni titi


Iru iriri ti mori gba la won kori

Sugbon anu ti morigba woko ri gba


Comments

Popular posts from this blog

Soundcheck Africa ft. Tim Godfrey and Xtreme - Living God Lyrics

Elijah Akintunde - Baba tin ba yin o mo ya Alaimore MP3 DOWNLOAD

Lizzy McAlpine – hate to be lame Lyrics