Qdot - Breakfast Lyrics


Qdot - Breakfast Lyrics

 Alagbe

Onilu yi joor oo

Omo eluku medemede

Amale afiliya

Emi nani

Omo omo moriamo


Woni oro dakun ma soko

E je n’so towo mi na

Edakun, nibo lowa

Nigba ti mon foju wi’na

Mohbad, imole ni mi

Oyinbo odun lenu mi

Tori Ibile ni mi

Teba ni ke mu eni afiola

Labalaba to se ere egun aso re afaya

I’m here for the money, not the fame

Ask about me i’m making money in the game

Ti ologini ba gun ori aja

A’rile aroka

Fuck anybody fuckable

I don’t care

Mo dabi messi

Mo dabi c’ronaldo

Momo sanwo ayanlu

Sanwo auanlu, Eruku mo bato

Lalude gan o’le pa abija

Omo ibadan to fi ewe senu

Sho’le bodija

Eta’kete Berimi lorita molete

Emi ko le’ma challenge

Mo da moda gan

Ata nimi ,mota,mota gan

Ina mi o mo’eni to da

Werepe nimi ema lo ja (Alagbe soro)

Award onigi, Ina igi lama fi da


Fuck your lyricist on the road, I’m the best

Taba ti ada, Fun’awon tiwa won oda

Woni wonogbomi, Speaker won ni o da

Mi o need akaba, Kin to ga to alaga

Ka dobale fun rara, Iyen o ni kama ga

Punch line foh won lenu lo

Gba !gba !gba !

Eshe may weather mo gbe wa

Dakun malo faya gba

Ayangbe Dangerous

Makinde pawo, Ju linda Ikeji lo

Ema pa’ohun mo’agoga, Eje n polongo

Esu lo lorita, Oluweri lo lodo

Don’t near me I’m bad!

Omo a’ka nigbo, Keru ba ara ona

Omo ma jegi je’eniyan

Oriki baba mi ni

O’kami lara gan, O sho ju abu abel

Shebi ka rin po, Yiye ni yeni

Ko’de niye gbogbo yin

Ewure loma gbo ogo yin

Boku owo kan Adan mafi rogi

Kole buru titi

Ki’omo alapata mi wa jegi

Wonipe mariwo lari, Pe’egun nbo

Nigbati egun ri wa gan egun ngbon

Edakun ,shey eye adan ni

Abi eye gunugu

Woni awon mu eye bo lapo

Eye tuti ku, ba ran ni ni’she eru

Ama fi tomo je babalawo ti o ja

Loma pada toroje, Bi’ise kan o lomo

Ise kan lonlo ti o ba jawo lori dating

Gbe rori ppp

Woni, acapella re dun

Dakun ma fi ilu si, salad mi

Lo fe bami fi’iru si

Ogun ti o je, Shebi ewe e’loku kan

Oba ni mi Alagbe’’o re bi kan kan

Kabiesi o

Omo ajana


Comments

Popular posts from this blog

Soundcheck Africa ft. Tim Godfrey and Xtreme - Living God Lyrics

Elijah Akintunde - Baba tin ba yin o mo ya Alaimore MP3 DOWNLOAD

Lizzy McAlpine – hate to be lame Lyrics