A Christmas carol written in December 1988 in the highlife style. This performance is by members of All Saints' Church Choir conducted by their music director David Aina, in Yaba, Lagos, Nigeria on 21 October 2013. This piece is popular with choirs all over Nigeria and abroad during the Christmas season.
If You need best Christmas carol songs in Yoruba Language for Choirs. This song is for you.
Download Eje Kajoyo.mp3 (3.52 MB)
David Àìná - Ẹ Jẹ́ Ká Jọ Yọ̀ (Let Us All Rejoice) Lyrics
Ejekajo yo kafijo si o
Abi olugbala kan fun wa
Eyin Onigbagbo E ho eyo
Aaa bi Jesu Olugbala
(Chorus)
Awa kio o oba mimo
Awa juba fun oba Ogo
Eyin Onigbagbo Eho eyo
Abi Jesu Olugbala
Awa Ki o o Oba mimo
Awajuba fun O oba ogo
Eyin onigbagbo e oh eyo
Abi Jesu Olugbala
(keyboard interlude)
(Female)
Ijoba yoo wani ejika re
Oun ni oba awon oba
Oun ni yoo joba titi aye o
Alade Alafia
(Chorus)
Awa ki o oba mimo
Awa juba fun o oba ogo
Eyin onigbagbo eho eyo
Abi Jesu Olugbala
Awa ki o oba mimo
Awa juba fun o oba ogo
Eyin onigbagbo eho eyo
Abi Jesu Olugbala
(Male)
Awon amoye meta igbaani
Won ri irawo kan didan
Irawo yi ni won nto leyin
Lati juba fun oba tuntun
Won wipe
(Chorus)
Awa ki o oba mimo
Awa juba fun o oba ogo
Eyin onigbagbo eho eyo
Abi Jesu Olugbala
Awa ki o oba mimo
Awa juba fun o oba ogo
Eyin onigbagbo eho eyo
Abi Jesu Olugbala
Awa ki o oba mimo
Awa juba fun o oba ogo
Eyin onigbagbo eho eyo
Abi Jesu Olugbala
(No Instrument)
Awa ki o oba mimo
Awa juba fun o oba ogo
Eyin onigbagbo eho eyo
Abi Jesu Olugbala