Osun State Anthem:
Isẹ wa fun ilẹ wa
Fun orilẹ ibi wa
kagbeja kagbega kagbega fayeri
Igbagbo wa ni pe base bẹru labọmọ
Kasisẹ kasisẹ kasisẹ kajọla
Isọkan atominira ni kẹjẹ ka maa lepaa
Tẹsiwaju ọpọire atohun to daraa
Ọmọ odu'a dide bọsi ipo ẹtọ rẹ
Iwọ ni, imọlẹ gbogbo adulawọ.
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.