This song is a powerful Spirit Filled Song by Apostolic Praise the full mp3 is now available Download and enjoy Lyrics Enjoy!.
Ijinle Ninu Ijinle Oseun O Lyrics
Mo gbe o ga o
Meta lokan Ijinle
Kabiyesi re o alaanu mi Ijinle
Ogbanre o Ijinle ni
Agbarare o Ijinle ni
Orukore o Ijinle ni
Okoja Oye eniyan Ijinle ni
Awamaridi o Ijinle ni
Ijinle ninu Ijinle mo gbe o ga o
Chorus
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ana mi soro Ose un o
Oni mi soro Oseun o
Olami asoro Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Verse 2
Kosoba bire o
Meta lokan Iwoni Ijinle
Omowo jade Lenu eja o Koyeniyan toriwoni Ijinle
Agbarare o baba Ijinle ni
Ogbanre o Ijinle ni
Okoja Oye eniyan Ijinle ni
Won wawawa won o ri o Ijinle ni
Kolafiwe o rarara Ijinle ni
Ijinle ninu Ijinle mogbe o ga o
Chorus
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ana mi soro Ose un o
Oni mi soro Oseun o
Olami asoro Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o
Ana mi soro Ose un o
Oni mi soro Oseun o
Olami asoro Ose un o
Ijinle Ninu Ijinle Ose un o