Iro Ayo by Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola mp3 download

 

Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo
(toc)

Download And Enjoy This New Mp3 Song!


Download Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo Audio


Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo Lyrics Video


Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo Lyrics Text

Verse 1
Iro Ayo La o ma gbo nile wa
Sekere ilole ekun
Igbagbo lo so’wa da’segun
Let them know pa’loluwa

Awa oni loju ekun La’ye
Awa oni lereke ose
Ore ofe Oluwa towa
Let them know pa’loluwa

Enu ope wa o’gbolude
Orun si ayo de s’aye
Ayo Olorun s’a lagbara wa
Won ti mo pa’loluwa

Chorus
Iro Ayo eh eh eh eh iro ayo eh
Iro Ayo lawa nfe o iro ayo eh
Iro Ayo ninu ‘le wa
Iro Ayo nirin ajo wa
Iro Ayo lori ise wa
Iro Ayo eh eh
Iro Ayo ninu ‘le mi
Iro Ayo nirin ajo mi
Iro Ayo lori ise mi
Iro Ayo eh eh

Verse 2
Once has He spoken
Twice have i heard
All power belong to GOD
Sing His praise with a shout of joy

Mimo Loluwa Mimo
Gbogbo aye kun fun ogo re Mimo
Awon Orun won wa riri Mimo
Almighty lo’lorunwa

Ayobami Ayomide
Ayomipo Ayomikun
Gbogbo Ayo ni mo kojo sir
Igbala Ayo ti wole de

Chorus
Iro Ayo eh eh eh eh iro ayo eh
Iro Ayo lawa nfe o iro ayo eh
Iro Ayo ninu ‘le wa
Iro Ayo nirin ajo wa
Iro Ayo lori ise wa
Iro Ayo eh eh
Iro Ayo ninu ‘le mi
Iro Ayo nirin ajo mi
Iro Ayo lori ise mi
Iro Ayo eh eh

Vamp
Ayo Ayo Ayo
Ayo Ayo nise

Vamp Adlib
Ayo
Ayo ni mo gbede
Eni ba rimi e gb’ayo
Eni ba gbo mi e gb’ayo
Oun mbase ayo
Ayo ni mo gbede
Gbogbo oun mo dawomile
Lo yori si’re
kiise mimose
Ore Ofe s’a
Ore Ofe s’a o
Eh eh eh eh
Ayo Ayo ni’se
Tags:Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo Mp3,Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo mp4, remix. cover, instrumental,Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo video,Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo TikTok,Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo radio edit,Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo music, 2022,Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo lyrics,Mike Abdul Ft. Omotola Jaiyeola - Iro Ayo album
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.

Post a Comment

0 Comments
* Please Don't Spam Here. All the Comments are Reviewed by Admin.

Ads Area

Disclaimer: All The Lyrics, Stories, Hymn, Poem & Anthem on Wikilyrics are submitted by various people and they have right on the contents they submitted, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download. If you feel one of your asset should not be here please request take down.