Tope Alabi mimo l'oluwa lyrics

Mimo Loluwa
Mimo
Angeli won mi ke
Awon Orun mi ke
Mimo
Egbageje irawo
Mimo
Mimo Loluwa
Mimo
Angeli won mi ke
Awon Orun mi ke
Mimo
Agbagba merinlelogun
Lorigun mererin aye o
Mimo
Atoke atile
Mimo
Se ni won nke tantan o
Mimo
Ta ni yo gori Oke oluwa
Mimo
Tabi tani yo duro nine
Mimo
Eni to ni owo Mimo, ati aya funfun
Mimo o loluwa
Mimo o Mimo o Mimo o
Mimo o fun fun nene ni
Mimo
Kabiyesi eledumare Oba Mimo
Oba NLA
Gbogbo aye e teriba fun Oba adari hurun
Oba to ni emi inu eniyan pata
Onikokoro aye lowo
Adagagodo emi gbogbo eniyan
Olukangun orun, ajosun edumare
Jigbinigbin, awuwo bi ate ileke
Mimo
Opa tirin kanle o kan orun
Ajosun edumare, minimini ojo to njara o deyan
Mimo
Orun wawa nigba to padabo sipo
Olorun to sosupa dale torutoru
Oba toun Soun gbogbo lasiko lasiko
Oba to let feyin eni ti, ta le feyin re ti laelae
Are NLA, Oga tenikan o bi
To bimo Kari aye porogodo
Olowori gbogbo aye, orogodigo baba awon eru
Mimo Mimo
Oniwa funfun, oba adake se in,
Tenikan o le se un si
Ninu ogo gangan lo ti fohun
Ologo to ju Ogo lo ni
Mimo.
Kabiyo o si, emi o je fi osere, afi eni to be fegba query lido re.
Mi o je foju di o
Oba ti o se wo loju wo
O ti e leti, ai le dibaje ni o
Baba NLA Ku Baba mi
O le pin yikin
Mimo
Gbogbo eni to be mi riri Oluwa, e Teri ba
Ewa riri fun Oba tite re ki si
Ibere at opin, Olorun ajanaku, tin mi gbo kijikiji
Mimo
Tabubu, tale bu tan, pupo si ni gbogbo ojo
Eje ka sale fun Oba rere ta ba mo riri
Emi inu awon woli
Atobitan, alainiye, popo koja riri
Terere koja kika, gungun lailopin
Ailetuwo, adaun ro, adaun se, adaun so
Oluwa inu awon orun, Oke NLA, arogunmatidi
Arabaribiti, aribirabata
Ejinkota biko yingirin
Ojo foke bi koyegere
Oke o le SA, Oke o le he
Koseni to le no aditu re, Olodumare
Iwo Lodi Iwo lo le tu, Oba NLA gbogbo agbaye loun
Teriba fun o baba Agba
Gbangba gbangba, jaranjaran, fenfefenfe
Iba o iba
Iwọ lodi Iwọ lo lè tu,
Ọba nla gbogbo àgbáyé lòún tẹriba fún ọ baba Agba
Gbángba gbángba, jaranjaran, fenfefenfe
Iba o iba...
Mímọ L'oluwa
Mímọ
Angẹli wọn mi ke
Mímọ
Àwọn Ọrùn wọn mi ke
Mímọ
Egbaagbeje ìràwọ
Mímọ

Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.

Tags

Post a Comment

0 Comments
* Please Don't Spam Here. All the Comments are Reviewed by Admin.

Ads Area

Disclaimer: All The Lyrics, Stories, Hymn, Poem & Anthem on Wikilyrics are submitted by various people and they have right on the contents they submitted, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download. If you feel one of your asset should not be here please request take down.