1. Ji Okan mi, ba orun ji,
Mura si ise ojo Re.
Mase ilora, ji kutu.
K'o san 'gbese ebo oro
2. Ro gbogb'ojo t'o fi sofo
Bere si rere 'se loni
Kiyesi 'rin re l'aye yi,
Ko si mura d'ojo nla ni.
3. K'oro re gbogbo j'otito,
K'okan re mo b'osan gangan
Mo p'Olorun nso ona re
O mo ero ikoko re.
4. Nipa 'mole ti nt'roun wa
Tan 'mole na f'elomiran
Jeki ogo Olorun 'han
Ninu ife at'orun yin
Do you Love Wikilyrics? Drop Comments & and follow us on Instagram
0 Comments