1. Wa s'adura ooro,
Kunle k'a gbadura,
Adura ni opa Kristian,
Lati b'Olorun rin
2. L'osan, wole labe
Apat'ayeraye,
Itura ojiji Re dun
Nigba t'orun ba mu
3. Je ki gbogbo ile
Wa gb'adura l'ale;
Ki ile wa di t'Olorun
Ati 'bode orun
4. Nigbat' od'oganjo,
Je k'a wi l'emi pe,
Mo sun, sugbon okan mi ji,
Lati ba O s'ona
AMIN
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.