Iya ni wura, iye biye
ti eyan kole f’owo ra
Iya ni wura, iye biye
ti eyan kole f’owo ra
Simi - Iya Ni Wura (Cover) Lyrics
Oh loyun mi fun oshu mesan
oh kpon mi fun odun meta
Iya ni wura, iye biye
ti eyan kole f’owo ra
owuro titi da’ale
o’oh fi adura boh mi o
iya mo ki eh ku ishe o
iya ku itoju mi
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.