1. 'Mole wa l'afonifoji
'Mole wa l'ori oke
Jesu l'O mu wa s'aye
Okukun yi,
'Mole wa l'ara itanna
To ndagba l'eba odo,
Imole wa ni 'bikibi ti mo nlo;
'Mole, Mole t'ife Re orun,
'Mole, mole, itansan orun
'Mole, mole, li aye wa yi,
'Mole, mole, l'ona ani gbogbo
2. Imole wa lori pada
Ati l'ori koriko
Nibiti awon eye nkorin iyin;
Imole wa lori oke,
'Mole wa ni petele
Je ki gbogbo eda jumo korin 'yin
3. B'aye tile kun fun 'mole
To si ntan l'ojojumo,
Okan pupo wa n'nu okunkun sibe,
Ti ko gb'oruko Jesu ri,
Tabi ife 'yanu Re,
Je ki a fi oro Re ran won l'owo
AMIN
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.
Disclaimer: All The Lyrics, Stories, Hymn, Poem & Anthem on Wikilyrics are submitted by various people and they have right on the contents they submitted, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download. If you feel one of your asset should not be here please request take down. (alert-warning)