1. Baba, a sope 'toju Re,
T'o f'alafia kun 'le wa;
Odo Re ni won ti san wa
Owo Re l'o si ngbe won ro
2. Olorun, t'o ye k'a ma yin,
L'a nkepe ninu ile wa;
Oluwa orun, ti ko ko
Lati ma gbe ile aye.
3. Jek'olukuluku 'dile
Ma kepe O tosan-toru;
K'a ko omo at' om'odo
L'ofin at'ore-ofe Re.
4. Beni k'iran ti mbo ma so
T'ola ooko Re t'o logo,
Titi gbogbo wa y'o fi lo
Dapo mo idile t'orun
AMIN
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.
Disclaimer: All The Lyrics, Stories, Hymn, Poem & Anthem on Wikilyrics are submitted by various people and they have right on the contents they submitted, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download. If you feel one of your asset should not be here please request take down. (alert-warning)