Elijah Akintunde - Baba tin ba yin o mo ya Alaimore MP3 DOWNLOAD

Elijah Akintunde - Baba tin ba yin o mo ya alaimore MP3 DOWNLOAD

Elijah Akintunde - Baba tin ba yin o mo ya Alaimore


Elijah Akintunde is an anointed Man gospel Singer who is respected for his unique style of singing. Akitunde, who has been singing for 19 drops a praise jam titled "Baba tin ba yin o mo ya Alaimore" which is Translated to Father I'm Ungrateful If I Do not Praise You in English

Download The Video, Lyrics and MP3 Below.


Baba tin ba yin o mo ya Alaimore Full Lyrics


Baba Tin ba yin o moya Alaimore
Jesu Tin ba yin o moya Alaimore
Ilaji Akoko Odunyi o mo laaja
Ninu Ewu Eru Iku pelu Idagiri
Aanu mori gba Ogun ti gbawon kan mi

Baba Tin ba yin o moya Alaimore
Jesu Tin ba yin o moya Alaimore
Ilaji Akoko Odunyi o mo laaja
Ninu Ewu Eru Iku pelu Idagiri
Aanu mori gba Ogun ti gbawon kan mi

Awon kan nbe logba were
Emi nbe loode mi
Awon kan nbe logba ewon
emi nbe loode mi
Awon kan nbe ni Isolation
emi nbe loode mi
Awon kan nbe ninu Ide
emi nbe loode mi

Ninu Ewu Eru Iku pelu Idagiri
Aanu mori gba Ogun ti gbawon kan mi

Baba Tin ba yin o moya Alaimore
Jesu Tin ba yin o moya Alaimore
Ilaji Akoko Odunyi o mo laaja
Ninu Ewu Eru Iku pelu Idagiri
Aanu mori gba Ogun ti gbawon kan mi

Baba Tin ba yin o moya Alaimore
Jesu Tin ba yin o moya Alaimore
Ilaji Akoko lOdunyi o mo laaja
Ninu Ewu Eru Iku pelu Idagiri
Aanu mori gba Ogun ti gbawon kan mi

Ogun ti gbawon kan mi
Ogun ti gbawon kan mi
Ogun ti gbawon kan mi

Ninu Ewu Eru Iku pelu Idagiri
Aanu mori gba Ogun ti gbawon kan mi

Baba Tin ba yin o moya Alaimore
Jesu Tin ba yin o moya Alaimore
Ilaji Akoko lOdunyi o mo laaja
Ninu Ewu Eru Iku pelu Idagiri
Aanu mori gba Ogun ti gbawon kan mi
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.

Post a Comment

0 Comments
* Please Don't Spam Here. All the Comments are Reviewed by Admin.

Ads Area

Disclaimer: All The Lyrics, Stories, Hymn, Poem & Anthem on Wikilyrics are submitted by various people and they have right on the contents they submitted, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download. If you feel one of your asset should not be here please request take down.