CACGHB Yoruba Hymn 23
1. Iwo imole okan mi, Ni odo Re, oru ko si,
Ki kuku aye ma bo O,
Kuro l'oju iranse Re.
2. Ni gba t'orun ale didun
Ba npa ipenpe 'ju mi de,
K'ero mi je lati simi,
Lae l'aya Olugbala mi.
3. Ba mi gbe l'oro tit'ale
Laisi Re, emi ko le wa,
Ba mi gbe 'gbat'ile ba nsu,
Laisi Re, emi ko ke ku.
4. Bi otosi omo Re kan
Ba tapa s'oro Re loni,
Oluwa, sise ore Re,
Ma je k'o sun ninu ese
5. Bukun fun awon alaisan,
Pese fun awon talaka,
K'orun onirobinuje
Dabi orun omo titun
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.