CACGHB Yoruba Hymn 24 L'oju ale 'gba't orun wo


1. L'oju ale 'gba't orun wo,
   Won gbe abirun w'odo Re,
   Oniruru ni asisan won,
   Sugbon won f'ayo lo' le won

2. Jesu a de l'oj' ale yi,
   A sun m'O t'awa t'arun wa,
   Bi a ko tile le 'ri O,
   Sugbon, a mo p'O sunmo wa.

3. Olugbala, wo osi wa,
   Opo nsaisan, opo nk'edun,
   Opo ko ni 'fe si O to.
   Opo n'ife won si tutu.

4. Opo ti ri p'asan l'aye
   Sibe nwon ko f'aye sile,
   Opo l'ore ba n'inu je,
   Sibe won ko fi O s'ore

5. Ko s'okan ninu wa t'o pe
   Gbogbo wa si ni elese,
   Awon t'o si nsin O toto
   Mo ara won ni alaipe

6. Sugbon Jesu, Olugbala,
   Eni bi awa ni 'Wo 'se
   'Wo ti ri 'danwo bi awa
   'Wo si ti mo ailera wa.

7. Agbar' owo Re wa sibe,
   Ore Re si ni agbara,
   Gbo adura ale wa yi,
   Ni anu, wo gbogbo wa san.
AMIN

Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.

Post a Comment

0 Comments
* Please Don't Spam Here. All the Comments are Reviewed by Admin.

Ads Area

Disclaimer: All The Lyrics, Stories, Hymn, Poem & Anthem on Wikilyrics are submitted by various people and they have right on the contents they submitted, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download. If you feel one of your asset should not be here please request take down.