1. 'Wo imole larin okun aye,
Ma sin mi lo;
Okunkun su, mo si jinna s'ile,
Ma sin mi lo;
Nko s'aferi ola bi y'o ti ri,
To ese mi, 'sise kan to fun mi,
2. Nigba kan ri, emi ko be O pe
K'O sin mi lo,
Beni nko fe O, sugbon nigba yi,
Ma sin mi lo,
Afe aye ni mo si nto leyin,
Sugbon Jesu, ma ranti igba ni.
3. Ipa Re l'o ti ndi mi mu, y'o si
Ma sin mi lo.
Ninu ere ati yangi aye,
Ma sin mi lo
Titi em'o fi ri awon wonni
Ti mo fe, ti won ti f'aye sile
AMIN
Please Kindly drop a comment, Corrections and suggestions. Your Comment is a motivating factor for wikilyrics to perform greatly.