CACGHB Yoruba Hymn 1 - WikiLyrics
Browse Lyrics A-Z
A | B | C | D | E | F | G | H | I | J | K | L | M | N | O | P | Q | R | S | T | U | V | W | X | Y | Z

CACGHB Yoruba Hymn 1

1. Olus'agutan eni Re
   Fi ara Re han wa,
   'Wo fun wa n'ile adura
   M'okan wa gbadura
2. Fi ami ife Re han wa
   So ireti wa ji
   Se'ri'bukun Re s'ori wa
   K'awa le ma yin O
3. K'ife ati alafia
   K'o ma gbe ile yi!
   F'irora f'okan iponju
   M'okan ailera le
4. F'eti igbo, aya 'gbase,
   Oju 'riran fun wa;
   Tan imole Re lat'oke
   K'a dagba l'or'ofe
5. K'a fi gbagbo gbo oro Re
   K'a f'igbagbo bebe
   Ati niwaju Oluwa
   K' a se aroye wa.
AMIN
Related Lyrics

Disclaimer: All The mp3 Lyrics on Wikilyrics are submited by various people and they have right on the contents they submited, all the Contents on our database is for educational purposes only and are made available for free download.