1. Imole oro didun yi,
Ji mi nin'orun mi,
Baba, ife Tire nikan,
Lo pa omo Re mo.
2. Nigbogbo oni, mo be O,
Maa se oluso mi,
Dariji mi, Jesu mimo,
Ki emi je Tire loni.
3. Wa se bugbe Re ninu mi,
Emi ore ofe,
So mi do mimo l'aye yi,
K'emi le roju Re.
AMIN
Do you Love Wikilyrics? Drop Comments & and follow us on Instagram
0 Comments